Ékísódù 37:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ́ọ̀bù mẹ́ta ni a se bí ìtànná alímóndì pẹ̀lú ìrùdí àti ìtànná wà ni ẹ̀ka kan, mẹ́ta sì tún wà ní ẹ̀ka mìíràn, bẹ́ẹ̀ ni ní ẹ̀ka mẹ́fẹ̀ẹ̀fà jáde lára ọ̀pá fìtílà.

Ékísódù 37

Ékísódù 37:16-21