Ékísódù 36:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní igun méjèèjì yìí, pákó méjì ni ó wà níbẹ láti ìdí dé orí rẹ̀ wọ́n sì kó wọ́n sí òrùka kan; méjèèjì rí bákan náà.

Ékísódù 36

Ékísódù 36:27-30