Ékísódù 36:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì pe Bésálélì àti Óhóábù àti gbogbo ọlọ́gbọ́n ènìyàn ẹni tí Olúwa ti fún ni agbára àti gbogbo ẹni tí ó fẹ́ láti wá sé iṣẹ́ náà.

Ékísódù 36

Ékísódù 36:1-9