Ékísódù 36:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo aṣọ títa mọ́kọ̀ọ̀kànlá náà jẹ́ ìwọ̀n kan ọgbọ̀n (30) ìgbọ̀nwọ́, ní gígá àti ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin ní fífẹ̀.

Ékísódù 36

Ékísódù 36:8-18