Ékísódù 36:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àádọ́ta (50) ajábó ní ó pa lára aṣọ títa kan, àti àádọ́ta ajábó ni ó sì lò pa ní etí aṣọ títa tí ó wà ní ọ̀kánkán ara wọn.

Ékísódù 36

Ékísódù 36:4-17