Ékísódù 35:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Mósè wí fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, “Wò ó, Olúwa ti yan Bésálélì ọmọ Úrì, ọmọ Húrì, ti ẹ̀yà Júdà,

Ékísódù 35

Ékísódù 35:25-33