Ékísódù 35:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì tún mú olóòrùn àti òróró ólífì wá fún títanná àti fún òróró ìtasórí àti fún tùràrí dídùn.

Ékísódù 35

Ékísódù 35:22-35