Ékísódù 35:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkúlùkù ẹni tí ó ni aṣọ aláró elésèé àlùkò, òdòdó àti ọ̀gbọ̀ dáradára, tàbí irun ewúrẹ́, awọ àgbò tí a rì ní pupa tàbí awọ màlúù odò, kí ó mú wọn wá.

Ékísódù 35

Ékísódù 35:20-31