Ékísódù 35:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ọjọ́ mẹ́fà ni kí ẹ fi ṣiṣẹ́, ṣùgbọ́n ọjọ́ keje yóò jẹ́ ọjọ́ mímọ́ fún yín, ọjọ́ ìsinmi ni sí Olúwa. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe iṣẹ́ kankan ni ọjọ́ náà ní a ó pa.

Ékísódù 35

Ékísódù 35:1-12