Ékísódù 35:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹpẹ tùràrí náà pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀, òróró ìtasórí àti tùràrí dídùn; aṣọ títa fún ọ̀nà ìlẹ̀kùn ní ẹnu ọ̀nà sí Àgọ́ náà;

Ékísódù 35

Ékísódù 35:13-22