Ékísódù 34:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹ̀ẹ̀mẹ́ta lọ́dún, gbogbo àwọn ọkùnrin ni kí ó farahàn níwájú Olúwa, Ọlọ́run Isirẹli.

Ékísódù 34

Ékísódù 34:19-33