Ékísódù 34:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe ohun tí èmi pa lásẹ fún ọ lónìí. Èmi lé àwọn ará Ámórì, àwọn ará Kénánì, àwọn ará Kítì àti àwọn ará Jébúsì jáde níwájú rẹ.

Ékísódù 34

Ékísódù 34:5-12