Ékísódù 33:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò rán ańgẹ́lì ṣáájú yín, èmi yóò sì lé àwọn Kénánì, àwọn ará Ámórì, àwọn ará Hítì, àwọn ará Pérísì, àwọn ará Hífì àti àwọn ará Jébúsì jáde.

Ékísódù 33

Ékísódù 33:1-12