Ékísódù 32:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wí fún Mósè pé, “Èmi ti rí àwọn ènìyàn wọ̀nyí, wọ́n sì jẹ́ ọlọ́rùn líle ènìyàn.

Ékísódù 32

Ékísódù 32:6-12