Ékísódù 32:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè rí i pé àwọn ènìyàn náà kòṣe e ṣàkóso àti pé Árónì ti sọ wọ́n di aláìlákóṣo láàrin àwọn ọ̀ta tí ó dìde sí wọn.

Ékísódù 32

Ékísódù 32:15-31