Ékísódù 32:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè dáhùn pé:“Kì í ṣe ariwo fún ìṣẹ́gun,kì í ṣe ariwo fún aṣẹ́gun;ohùn àwọn tí ń kọrin ni mo gbọ́.”

Ékísódù 32

Ékísódù 32:11-19