Ékísódù 31:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíwájú sí i, èmi ti yan Óhólíábù ọmọ Áhúsámákì, ti ẹ̀yà Dánì, láti ràn án lọ́wọ́. Bákan náà, èmi ti fi ọgbọ́n fún gbogbo àwọn oníṣẹ́ ọnà láti ṣe ohun gbogbo tí mo paṣẹ fún ọ:

Ékísódù 31

Ékísódù 31:1-9