Ékísódù 31:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì ti fi ẹ̀mí Ọlọ́run kún-un pẹ̀lú ọgbọ́n, agbára àti ìmọ̀ ní gbogbo onírúurú iṣẹ́ ọnà.

Ékísódù 31

Ékísódù 31:1-12