Ékísódù 30:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Árónì yóò sì máa jó tùràrí dídùn lórí pẹpẹ náà ní àràárọ̀, nígbà tí ó tún àwọn fítìlá náà ṣe.

Ékísódù 30

Ékísódù 30:1-17