Ékísódù 30:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe ìwọ̀nyí ní òróró mímọ́ ìkunra, tí a pò pọ̀ gẹ́gẹ́ bí olùṣe-òórùn dídùn tì í ṣe, Yóò jẹ òróró mímọ́ ìtasórí.

Ékísódù 30

Ékísódù 30:17-29