Ékísódù 30:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rẹ̀ ṣe déédé, kí ó jẹ́ ìdajì mítà ní gígùn, ìdajì mítà ní fífẹ̀ àti ìgbọ̀nwọ́ méjì ni gíga rẹ̀—kí ìwo rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀.

Ékísódù 30

Ékísódù 30:1-12