Ékísódù 30:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò máa wẹ ọwọ́ àti ẹṣẹ̀ wọn pẹ̀lú omi tí ó wà nínú rẹ̀.

Ékísódù 30

Ékísódù 30:18-27