Ékísódù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀ ni ańgẹ́lì Olúwa ti yọ sí i nínú ọ̀wọ́ iná ti ń jó láàrin igbó. Mósè rí i pé iná ń jó nínú igbó ṣùgbọ́n igbó kò run

Ékísódù 3

Ékísódù 3:1-6