Ékísódù 29:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìwọ yóò sì fi fìlà dé wọn ni orí. Nígbà náà fi ọ̀já àmùrè di Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀. Iṣẹ́ àlùfáà yóò máa jẹ́ ti wọn ní ìlànà títí ayé. Báyìí ni ìwọ yóò sì ya Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sí mímọ́.

Ékísódù 29

Ékísódù 29:3-15