Ékísódù 29:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀dọ́ àgùntàn kejì ni kí ìwọ ki o pa rúbọ ní àṣálẹ̀ ìwọ yóò sì ṣe sí í gẹ́gẹ́ bí ẹbọ jíjẹ àti ẹbọ mímu bí ti òwúrọ̀ fún òórun dídùn, ẹbọ tí a fi iná ṣe ni sí Olúwa.

Ékísódù 29

Ékísódù 29:39-44