Ékísódù 29:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bàyìí ni ìwọ yóò sìṣe fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ bí ohun gbogbo ti mo paláṣẹ fún ọ, ọjọ́ méje ni ìwọ yóò fi yà wọ́n sí mímọ́.

Ékísódù 29

Ékísódù 29:32-39