Ékísódù 29:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò sì jẹ nǹkan wọ̀nyí èyí tí a fi se ètùtù náà fún ìyàsímímọ́ àti ìsọdimímọ́ wọn. Ṣùgbọ́n kò ní sí ẹlòmíràn ti yóò le è jẹ wọ́n, nítorí pé mímọ́ ni.

Ékísódù 29

Ékísódù 29:25-43