Ékísódù 29:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú apẹ̀rẹ̀ ìṣù àkàrà aláìwú, èyí tí ó wà níwájú Olúwa, mú ìṣù kan, àkàrà tí a fi òróró dín àti àkàrà fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ kan.

Ékísódù 29

Ékísódù 29:17-31