Ékísódù 28:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti onírúurú ọnà ọ̀já rẹ̀, tí ó wà ni orí rẹ̀, yóò rí bákan náà, gẹ́gẹ́ bi iṣẹ́ rẹ̀, tí wúrà, ti aṣọ aláró, òdòdó àti ọ̀gbọ̀ olókùn wíwẹ́.

Ékísódù 28

Ékísódù 28:2-17