Ékísódù 28:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì gbọdọ̀ máa wọ̀ ọ́ nígbà tí o bá ń sisẹ́. A ó sì máa gbọ́ ìró àwọn agogo nígbà tí ó bá ń wọ ibi mímọ́ níwájú Olúwa àti nígbà tí ó bá ń jáde bọ̀, kí ó má ba à kú.

Ékísódù 28

Ékísódù 28:32-42