Ékísódù 28:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe pómégánátè ti aṣọ aláró, ti elésèé àlùkò àti ti òdòdó yí ìsẹ́ti ọ̀já àmùrè náà ká, pẹ̀lú aago wúrà láàrin wọn.

Ékísódù 28

Ékísódù 28:23-35