Ékísódù 28:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkúta méjìlá (12) yóò wà, ọ̀kọ̀ọ̀kan fún orúkọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì olúkúlùkù èdìdì àmì pẹ̀lú orúkọ ẹnìkọ̀ọ̀kan bí ẹ̀yà Ísírẹ́lì méjìlá.

Ékísódù 28

Ékísódù 28:19-31