Ékísódù 28:17-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Nígbà náà ni ìwọ yóò de òkúta iyebíye mẹ́rin sára ẹṣẹ̀ rẹ̀. Ní ẹṣẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí rúbì, tópásì àti bérílì wà;

18. ní ẹṣẹ̀ kejì émérálídì, sáfírù, àti díámóńdì;

19. ní ẹṣẹ̀ kẹta, lígúrè, ágátè, àti ámétísítì;

Ékísódù 28