Ékísódù 28:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìhà mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rẹ̀ se déédé—kí ó jẹ́ ìwọ̀n ṣẹ́ńtímítà méjìlélógún ní gíga àti ìwọ̀n ṣẹ̀ńtímítà méjìlélógun (22 centimeters) ní fífẹ̀ kí o sì ṣe é ní ìsẹ́po méjì.

Ékísódù 28

Ékísódù 28:15-17