Ékísódù 28:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti okùn ẹ̀wọ̀n méjì ti kìkì wúrà, gẹ́gẹ́ bí ọ̀já àmùrè kí o sì so ẹ̀wọ̀n náà mọ́ ojú ìdè náà.

Ékísódù 28

Ékísódù 28:9-23