Ékísódù 28:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ sì mú Árónì arákùnrin rẹ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, mú un kúrò ni àárin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ Nádáhù, Ábíhù, Élíásárì, àti Ítamárì, kí wọn kí ó lè sìn mí gẹ́gẹ́ bí àlùfáà.

Ékísódù 28

Ékísódù 28:1-7