Ékísódù 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aṣọ títa márùn ún ni kí ó papọ̀ mọ́ ara wọn sí apá kan àti mẹ́fà tókù sí apá ọ̀tọ̀. Yí aṣọ títa kẹfà po sí méjì níwájú àgọ́ náà.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:5-17