Ékísódù 26:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣe aṣọ títa irun ewúrẹ́ láti fi ṣe ibò sórí àgọ́ náà—kí ó jẹ́ mọ́kànlá papọ̀.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:1-10