Ékísódù 26:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bo àwọn pákó náà pẹ̀lú wúrà, kí o sì ṣe òrùka wúrà kí ó lè di ọ̀pá ìdábùú mu. Kí o sì tún bo ọ̀pá ìdábùú náà pẹ̀lú wúrà.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:22-32