Ékísódù 26:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní igún méjèèjì yìí, wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ méjì láti ìdí dé orí rẹ̀, a ó sì so wọ́n pọ̀ sí òrùka kan: méjèèjì yóò sì rí bẹ́ẹ̀.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:21-33