Ékísódù 26:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Asọ títa àgọ́ náà yóò jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan gígùn ní ìhà méjèèjì; Èyí tí ó kù yóò rọ̀ sórí ìhà àgọ́ náà láti fi bò ó.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:10-14