Ékísódù 25:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òróró olífì fún iná títàn, òróró olóórùn dídùn fún ìtasórí àti fún tùràrí olóórùn dídùn,

Ékísódù 25

Ékísódù 25:1-7