Ékísódù 25:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi ojúlówó wúrà se àwo àti ṣíbí rẹ̀, kí o sì ṣe àwokòtò àti ago pẹ̀lú fún dída ọrẹ jáde.

Ékísódù 25

Ékísódù 25:21-37