Ékísódù 25:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òrùka náà ko gbọdọ̀ jìnnà sí etí rẹ̀, kí ó lè gbá òpó mú nígbà tí a bá ń gbé tábìlì náà.

Ékísódù 25

Ékísódù 25:20-31