Ékísódù 25:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fi igi kaṣíà kan tábílì: ìgbọ̀nwọ́ méjì ní gígùn ìgbọ̀nwọ́ kan ní fífẹ̀, ìgbọ̀nwọ́ kan àti ààbọ̀ ní gíga.

Ékísódù 25

Ékísódù 25:16-24