Ékísódù 25:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ojúlówó wúrà ni kí o fi se ìtẹ́ àánú; ìgbọ̀nwọ́ méjì àti ààbọ̀ ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ kan àti ààbọ̀ ní fífẹ̀.

Ékísódù 25

Ékísódù 25:16-20