Ékísódù 25:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bo orí rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó wúrà, bò ó ni inú àti ìta kí o sì fi wúrà gbá etí rẹ̀ yíká.

Ékísódù 25

Ékísódù 25:7-17