Ékísódù 24:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè bu ìlàjì ẹ̀jẹ̀ ẹran sínú abọ́, ó sì fi ìlàjì tókù wọn ara pẹpẹ.

Ékísódù 24

Ékísódù 24:1-10