Ékísódù 24:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ògo Olúwa sì wà ní orí òkè Ṣí náì. Ìkùùkuu bo orí òkè náà fún ọjọ́ mẹ́fà, ni ọjọ́ keje ni Olúwa kọ sí Mósè láti inú ìkùùkuu náà wá.

Ékísódù 24

Ékísódù 24:14-17