Ékísódù 23:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò rán oyin ṣáájú rẹ láti lé àwọn ará: Hífì, Kénánì àti Hítì kúrò ni ọ̀nà rẹ.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:18-33